Ogbon Iseda Oro Oruko
1. Afomo ibeere: Awon wonyi ni amaa lo fun afomo ibere ti a ba seda oro-oruko a,a,e,e,e,e,I,I,o,oni,on,o,ati,ai,
a. Afomo ibere + oro ise
e + se = ese, o + gbon = ogbon ati + je = atije, on +ka = onka, ai + sun = aisun
b. afomo ibere ti oro ise + oro ise
I + tan + je = itanje ai + tun + se = aitunse a + ko + jo = akojo
d. Afomo ibere + oro ise + oro oruko
o + mu + oti = omuti ati + ko + ile = atikole
2. Afomo aarin
a. Iso + ku + so = isokuso
b. owo + si + owo = owosowo
d. Igba + de Igba = Igbadegba
e. Odun + mo + odun = Odunmodun
e. Eni + ki + eni = Enikeni
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.