Thursday, December 21, 2023

Ogun Pin pin Nile Yoruba

SHARE

Ogun toka si ohun ti ologbe fi oogun oju re ko jo nigba aye re. Ohun ini bee le je owo, ile, oko, , eru,omo, iyawo  tabi awon dukia miiran.


Ni ile Yoruba bi omo se le je ogun baba naa lo le je ti iya ra. Ogoji ojo leyin  ti oku ba ti ku ni won to le pin ogun re.
 Won yoo yan baba isinku o le je ebi to ba dagba julo, oun ni yoo seto isinku titi di akoko ti won yoo pin ogun. Baba isinku kii mu ninu ogun.


Ki ogun pinpin to waye, baba isinku ati awon amulegbe re yoo ti seto bi gbogbo nnkan  yoo fi lo ni irowo-irose. Ohun akoko ni lati da ifa lati mo ojo ti o ye ati akoko lati fi ijoko si.


 


AWON TI WON LETOO SI OGUN


Gbogbo awon omo oku ati awon omo iya re ti won je aburo ni won ni eto si ogun. Baba , iya, egbon oku ati iyawo ko ni eto lati pin ninu ogun oku ni ile Yoruba.


AKOKO TI A N PIN OGUN


Leyin isinku ni won yoo dajo ti won yoo pin ogun. Ogoji ojo gbodo pe ayafi ti ija ba wa ti won si fe fi pinpin ogun petu si ikun-sinu to wa nile.


OJO IJOKOO OGUN PINPIN


Ona ti a n gba pin ogun yato lati idile si idile. Awon miiran maa n pin ni olori-ojori.Olori-ojori ni pinpin ogun laaarin iye omo ti oloogbe bi. Akobi omokunrin ni yoo ko mu ogun, ti akobi omobinrin yoo si mu tele, leyin eyi ni awon toku yoo mu ogun.  Awon miiran si n pin in laaarin iye aya, eyi si ni a tun pe ni IDI-IGI. Pinpin ni ilana yii lo wopo julo ni ile Yoruba.  Ni ile Yoruba obinrin ti o ba bimo fun oko re ko leto ninu ogun oku.BI eru ba si bimo fun oloogbe, won maa n fun omo eru bee ni orun pupo nitori ile baba nikan ni o ni ko ni ile iya. Omo ale kii si ni eto si ogun ni ile Yoruba.


AWON OHUN TI A N JOGUN


1.   Awon nnkan to le tete baje


2.   Awon nnkan ti o le tete baje


3.   Aya oku


4.   Omo oku ti won ba kere


AWON OHUN TI A KII JOGUN


This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: