Orin ni afo ti a fi ohun to dun ko ni eti sita.
ORISIRISI ORIN IBILE
1. Orin ibi igbeyawo
2. Orin eremode
3. Orin oye jije
4. Orin ikomojade
5. Orin amuseya
6. Orin funeko iwa rere
1. ORIN IBI IGBEYAWO :
Eyi ni orin ti a n ko nibi ayeye igbeyawo, o je orin ti won fi n ko iyawo afesona tabi olomoge ni ogbon ati eko.
ANFAANI
i. n je ki obinrin mo iyi pipa ogo obinrin mo
ii. n je ki a ni emi imore si obi
iii. n ke ki omobinrin mo ojuse re si oko ati si ebi oko re
Apeere orin igbeyawo ni :- Baba mo n lo, fadura sin mi o. Ori iya mi bu lomo, esuru kii ya agan o.
2. ORIN EREMODE :- eyi ni orin to maa n waye laaarin awon ewe.
ANFAANI
i. wa fun idaraya
ii. n mu opolo ji pepe
iii. mu ki omode gbagbe abuku tabi iya ara won
iv. mu won mo Pataki itoju ara ati ayika
Apeere :- Orin boju boju,… Eni bi eni… We ki o mo…..
3. ORIN NIBI OYE JIJE :- eyi ni orin ti maa n gbo nibi ti won ti n se ayeye oye jije.
ANFAANI..
i. n je ki a mo bi a se le gbe igbesi aye iwa rere lawujo
ii. n je ka gbe asa abinibi laruge
4. ORIN IKOMOJADE : Eyi ni orin ti a n ko nibe ayeye ikomojade.
ANFAANI
i. n je ki a mo Pataki omo ikoko ninu ebi
ii. wa fun gbigbe asa wa laruge
5. ORIN EKO IWA RERE :- eyi je orin iwuri fun awon omode
ANFAANI
i. ma mu ki omode tepa mose
ii. ma ko omode ni iwa to to lati hu ni awujo
iii. maa n ko awon omode ni asa abinibi
Apeere :- Omo to mo iya re loju…….
6. ORIN IREMOLEKUN : – Eyi ni orin ti abiamo fi n ro omo eyin lekun.
ANFAANI
i. mu ki omo dake ekun
ii. je ona lati da omo laraya.
Apeere :- omo mi o, akurubele ku be……….
ORIN AMUSEYA :- Eyi ni orin ti awon osise maa n ko lenu ise.
ANFAANI
i. je ona idaraya
ii. mi ni mo riri ise eni
n je ki ole ji giri wa ise se.
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.