Tuesday, December 19, 2023

Oro Atokun Ninu ede Yoruba

SHARE
Àlàyé lórí Òrò atókùn ń gbé òwe Yorùbá léyìn pé '' bí a bójú tí a bómú, ìsàlè àgbòn làá Parí rè sí ''. 
Èyìí rí béè nítorí pé ohun tí a pè ní atókùn yìí jo ìsòrí Òrò ìse. Àbùdá Òrò ìse àti Òrò atókùn jora púpò láti fí so pé Òrò ìse ni, sùgbón ìsòrí Òrò tí ó dá dúró ni Òrò atókùn jé.
 Àwon Òrò tí a ń pé ní atókùn ni:
tí, fi, pèlú, ní, láti, fún, bá, sí.Àwon àpęęrę tó se àlàyé rè fún wa ní wònyìí.
Mo fò sókè Fún ayò
N ó lo sí ojà Ní àìpé.
A wà Ní ibí ó.
Túndé FI èrú gba ìbùkún
Fájémirókun FI owó mo Olorun
Àwon sójà ń TI ojú ogun Sambísa dé.
Alàájì ti dé LÁTI mókà.
Olóyè dé PÈLÚ ìlù àti Ariwo.

Bí a bá se Akíyèsí daada, a ó ri pé ègé kan ni Òrò atókùn máa ń ní, ó máa ń bèrè pèlú kóńsónántì, ó sì máa ń gba àbò. A ó ri wí pé àwon ìrísí àti ìhùwà si rè dá gégé bí Òrò ìse.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: