Thursday, December 21, 2023

Owo sise Nile Yoruba

SHARE

Owo sise ni a mo si karakata. O je okan pataki ninu ise  aje awon yoruba.
Pataki owo sise

1.     Owo sise ni n le ise danu, o si n soni dolowo

2.     O n je ki a ni ise lowo

3.     Owo kii je ki a sole

4.     O mu ni gbajumo ni awujo

5.     O mu ki oja okere wa ni arowoto wa

6.     O mu ki ire oko wo ilu ni opo yanturu

 

Orisi owo ti yoruba n se .

1.     AROBO/AGBATA : awon alarobo ni won n raja lowo oloko, won yoo wa ta ojo naa fun awon Alajapa leyin igba ti won ba ti fi owo le e.

2.     ALAJAPA : won n ra ojo lowo oloko tabi Alarobo, won yoo ta oja naa fun ara ilu. Awon oja bi :Elubo, ata,isu,gaari,agbado, abbl.

3.     Worobo/Wosiwosi : eyi ni awon ti won n taja pepeepe tabi worobo. Won le pate oja won tabi ki won kiri oja won. Awon oja bii :- Suiti,Bisikiti. Ose-iwe ati ifoso, Pako,Aso omode,abbl.

4.     OUNJE TITA- o leje ounje sise tabi tutu, won la pate tabi ki won kiri. Apeere ounje bee ni : isu, iresi,epo,ewa abbl.

5.     OSIN ERAN : awon onisowo kan wa ti won n ta eran osan lorisirisi bii : Ewure, adiye,agbo,igbin,aguntan,abbl.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: