OYUN NINI. ITOJU ATI OMO
Obinrin ti ko bimo ni leyin ojo pipe ni ile oko ni won n pe agan. Awon yoruba ka omo bibi si pupo, won gba pe ko si bi opo eniyan ti le po to ti ko ba bimo, aye asan ni oluwa re wa. Abiku nigba miran le so obinrin di agan.
OHUN TO N FA A KI OBINRIN MAA TETE LOYUN
1. Bi nnkan osu obinrin baal ami tabi ti o n se segesege
2. Oyun sise tabi isilo ogun ti o ba ile omo je
3. Inu gbigbona
4. Ti obinrin ba ya akiriboto tabi oko kura
5. Ti nnkan omokunrin ba son
6. Aisan atosi tabi jerijeri lara tokotaya
OHUN TI O LE FA OYUN BIBAJE LARA OBINRIN
1. Aarun atosi olojo pipe
2. Eda
3. Awon Aje
4. Ise agbara
Itoju oyun laarin osu kinni si iketa ko le. Obinrin ko gbodo naju. ki oyun re maa baa wale. oko gbodo maa ran an lowo ninu ise ile. leyin osu keta ni oko aboyun yoo to wa onisegun ti yoo maa toju aboyun lati ri pe oyun naa ko baje tabi bi omo ti ko pe ojo.
A ajo fun aboyun leyin osu keta ni wonyii
1. OYUN DIDE : -Bi oyun ba di osu meta ni won o ti dee . Ki oyun maa baje lara obinrin ni won se maa n de oyun titi di akoko ti yoo bimo. Osu kesan-an, tabi to ojo b ape ni won yoo to ja oogun na asile, ki aboyun si bimo.
2. EEWO KIKA FUN ABOYUN : – Awon nnkan ti asa yoruba ko gbe aboyun laaye lati se ni an pe ni eewo. ona lati daabo bo oyun inu ni o bi eewo. Bi apeere
I.Alaboyun ko gbudo sise lile
II.Alaboyun ko gbudo rin ninu orun tabi ni oru
III.Ko gbodo je igbin, ki om ore maa ba dota
IV.Oko aboyun to je ode gbodo sora pipa eranko abami ni akoko ti iyawo re wa ninu oyun.
3. ASEJE FUN ABOYUN
4. AGBO WIWE ATI MINU : Onisegun agbebi yoo se orisirisi aseje tabi agbo fun aboyun
5. OSE AWEBI ATI AGBO ABIWERE : Ti oyun ba ti osu mejo onisegun yoo fun-un ni agbo abiwere, eyi yoo mu ara de.
ITOJU OYUN TI ODE ONI
Bi obinrin baa ti loyun ni yoo ti lo fi oruko sile ni ile iwosan ijoba ipinle tabi ibile ni agbegbe re fun ayewo ati itoju. Alaboyun yoo maa lo si ile iwosan bee loorekoore gege bi adehun tito ti yoo fi bimo.
I. Idanilekoo ati ayewo omo inu
II. Oogun ati abere
III. Ounje afaralokun
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.