Pataki Esin lawujo Yoruba

PATAKI ESIN LAWUJO YORUBAEsin se Pataki lawuojo Yoruba fun awon id wonyii1.     Esin je ki a mo orirun ara eni

2.     O n ko ni ni iwa-bi-Olorun

3.     O n ko ni ni ilana akoso ti o to lawujo

4.     O n se atokun fun orin kiko, iji jjijo ati ewi kika

5.     Esin je amu ogbon fun awon onkawe, akotan ati akewi

6.     O n se okunfa irepo, ibagbepo,alaafia ati ibale okan

O n se okunfa ikoni-ni-ijanu, isowahu ati iseto ni awujo.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Post a Comment

Translate