Tuesday, December 19, 2023

Yoruba Self Protection

SHARE
Ojú ni alákàn fi ń sórí ni Òrò ààbò ara-ęni. Kójú má ríbi àìjàfara ni oògùn rè. Yorùbá kò fi ààbò ara ęni jáfara rárá. Onírúurú aájò àti oògùn ni Wón fi ń sààbò ara won.Lára àwon oògùn bęè ni kánàkò èyí tó lè so ìrìnàjò tó lé gba òsán méta òru méta di ojó kan péré láìsí ewu.
Nínú aájò fún ààbò náà ni òkígbé, ìfúnpá, àti óńdè. Nígbà míràn,Wón le lo àgbékórùn pèlú dàńsíkí àti fìlà; Egbé nìyęn.
Bí àpęęrę, láyé àtíjó Aláàfin òyó gbó pé oba ìlú kan, ìyen Òkukù ní ìpínlè Òsun ní oògùn púpò. Aláàfin pàse pé kí Ó wá fi Ojú kan òun, bí ó ti dé ààfin ni Wón so fún un pé kí ó jókòó lórí ęní, kò mo pé Wón tí gbé kòtò jínjìn sábé ęní. 
Bó se jókòó ni ęní jìn fìn-ìn.Ó kégbe ńlá ''hèéè! kíké tó ké, inú yàrá rè ní ààfin rè ló bá ara rè lÓkukù.Egbé nìyęn.


 Ààbò tó péye ló jé láàárin àwon Yorùbá (Ògúnsínà 2012).À ó má tè síwájú lósè tí ń bò ire!.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: