Sunday, January 28, 2024

Owe ATI akanlo ede Nile Yoruba

SHARE
Owe ATI akanlo ede Nile YorubaEde Yoruba rorun lati ko ati lati gbo pelu. Akeko ni lati fi okan ati eti sile dada, ki o baa lee mo pelu irorun.

 Bi eniyan ba sunmo awon agba, yoo tete gbo awon owe ati asayan oro ijinle ede Yoruba, bakannaa ni kika re yoo si rorun, nitoripe faweli (vowels) re farakinra pelu oyinbo.

Awon ami ti o wa lori oro kookan, ni nmu aka yeni to ni itumo t’o kun rere wa.
 ami isale – sokoto, eru, kokoro, fila, isale (Trouser, Fear, Papa, Cap, bottom)ami oke – digi, papa, dupe, sibi, kokoro (mirror, grassland, female name, spoon, key)
Oro ti ko ba ni ami Kankan lori ni ami aarin – aso, esin, emu, pupa, omi. (cloth, horse, palm, wine, red, water)A ma nlo owe tabi gbolohun atenumao lojoojumo nibigbogbo, nigbagbogbo tabi lore koore.
Awon agba ati odo t’o ba m’ oye je orisun owe tabi asayan oro ijinle. Bi eniyan ba sunmo won, onitohun yoo ni itumo t’o kun – ile eko yi, enu agba ni o. 
1. Awon Owe To Wa Fun Esin – Sise Ife Ati Liana Olorun (Godliness)

   Olooto kii l’eni sugbon ko si sun si’ poi ka.


   B’o l’aya, o se’ka, b’o ba ranti iku Gaa k’o sotito.   A dun-un se bi ohun ti Olorun l’owo si, a soro se b’ohun t’ Olorun ko l’owo si.
   B’oore po, a di bi.
2. Awon Owe Fun Ise Sise (Industry) Oju boro ko ni a fi ngb’omo lowo ekuro. A gbe’ le ya’na, ni a gb’ oko yaa’ run. Igba yi l’aaro, t’ arugbo nko’ gba. O ko s’emu l’o gbe, o ko t’ eguro l’ofa, o de di ope, o gb enu s’oke, ofe ni nro?

3. Awon Owe Fun Iwa Rere (Decency)
   Ajobi ko f’ eke.
   A wo ‘lu ma te, iwon ara re lo mo.
   Falana gbo tie, t’ara eni l’a ngbo.
   B’ o see re, o ban be.

4. Awon Owe Fun Ibowo Agba (Respect)
   Ai f’agba f’enikan, ko j’aye o gun.
   Enu agba l’obi ngbo.
   A gba ko si, ilu baje, bale ile ku, ile d’ahoro.
   Ai feni p’eni, ai f’eniyan p’eniyan, l’ara oko fin san bante wo lu.

5. Awon Owe Fun Aibikita (Carelessness)
   Enu ko sun won, elenu pon la.
   Ibi ti a r’aye l’a je, b’ ojo npa o, maa to sara.
   Ara o bale, olori arun. Oju yo ro, ni’ rore nso.
6. Awon Owe Fun Awon Ika (Wickedness)
   A k’eyin je, ko mo pe’ di nro adie. A di’kuta s’eru eni o fuye.
   B’ eniyan ba nyo’ le da, ohun buburu a maa yo se.
   B’oo ba, o pa, b’ o bu l’ese.

7. Awon Owe Fun Igboya (Courage)
   Ai lee ja, ni won o bi mi ni le yi. Yijo ekun, t’ojo ko.
   Omo ajanaku ko ni ya’ra, omo t’ekun bi, ekun ni o jo.
   Piri l’olonge nji, a kii b okunrun eye lori ite.
8. Awon Owe Fun Ifowosowopo (Cooperation)
   Ajeje owo kan ko gb’eru d’ori. A kii l’agbara to kekere sikekji.
   Aja t’o ba l’enu l’ehin lo np’obo, eyiti ko l’eni l’ehin, a p’aaya.
9. Awon Owe Fun Eniti O Nse ’Mele (Laziness)
   A de bi eyin ma si agba ole.
   Akuko ko, ole pose.
   Ole ba ti, o gb’odo nla.
   Ibi ti a r’aye l’a nje, b’ojo npa o, maa to sara.
10. Awon Owe Ti A Fi Npon Ni (Flattery)
   Yojo l’enu araye nda.
   B’aye ba t’ ori eni, iwa ’baje l a nhu.
   Eni t’araye fi np’Adegun, naa ni won fi np’Adeogun.
   Mo dagba nko S’oge mo, owo ni ko si

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: