21 things that would not make spiritual work to work

AWON NNKAN TI KI NJE KI OGUN-AJO SISE LARA ENIYAN.
(1) Eni ti owo Aiye ba wa lara re, to ba lo Ogun, tabi to ba se Ogun fun rara re, ko le sise
Anyone with bad mark on their body
(2) Aini Imo to peye lori Ogun ti a Nse, ati lilo re
Not having proper knowledge of the spiritual work giving to us 
(3) Aitele Ilana ati Igbese lori awon Ogun ti a nse
Not following the instructions giving to us
(4) Ai lo ojulowo awon Eroja to peye, Ayederu Eroja
Not using quality ingredients while preparing the spiritual work
(5) A i ni Igbagbo (Faith) lori awon Ogun ti a Nse
Not having faith in it 
(6) Ogun ti Eroja re, ko ba ti pe daadaa, Ko le sise
A spiritual work that is not having enough ingredients
(7) A i bikita Eleda eni to fe se Ogun, boya Eleda re ro mo Ise to fe se
Without consultation of the spiritual head may be the head doesn’t want that particular spiritual work 
(8) Okunrin ko gbodo ma ba Obinrin ni Ibalopo (Se..x) lati eyin (Doggy Se..x)
Stop having doogy still during intimacy 
(9) Jije Nnkan Eewo, O ma Nfa ki Ogun ma sise lara Eyan
Eating the taboos
(10) Ko dara ki eni to ba Nlo Ise Ajo maa je:- Obe Ila, ati Eran Okete ni gbogbo igba, Nitori pe, awon Ounje naa ma Nba Ise Ajo Ogun je lara eyan
Stop eating any draw soup 
(11) Eni to ba ni Imule awon Agba lara, Ko dara ki eni naa ma je Eran Abiye bi:- Adie, Pepeye, Tolotolo ati Eye, Ki onitohun ba maa ri ija awon Iyami Eleye (Osoronga). Nitori pe, ODU OSA-MEJI ELEYE ni
(12) Okunrin ko gbodo ma fi Ise to ba lagbara ba Obinrin ni Ibalopo (sex)
(13) Bi Obinrin ba Nse Nkan Osu-(Menstruation) re lowo, Okunrin ko gbodo ba ni Ibalopo (S..ex), Ki gbogbo ogun to wa lara re, ba ma baje
Don’t have intercourse with a menstruating woman 
(14) Bi Obinrin ba Nse Nkan Osu- (Menstruation) re lowo. ko gbodo lo Ise Ajo lasiko naa, Ki awon Ise Ajo naa ba ma baje
When a woman is menstruating she must not use spiritual work 
(15) Bi Okunrin ati Obinrin ba da Ato- (Sperm) sara loju Ala. Ti won ba lo Ise Ajo, ko le sise
(16) Ko dara ki Okunrin ati Obinrin ma to (Urinate) sori Ewe ni gbogbo igba, Ki Nje ki Ogun sise lara eyan
(17) O dara ki Eyan ma lo ISE AJEGUN TODAJU ni gbogbo igba. Ki gbogbo Ise Ajo ti Eyan ba Nse le tete ma sise lara ni kiakia
(18) E je ka sora lati maa ba won bu awon AJE, EMERE ati OSO (Witches & Wizard)
(19) E ma je ki Kainkain ti a fi Nwe ma jabo lowo wa ni gbogbo igba ti a ba Nwe Ose lowo, Nitori pe, o ma Nba Ise je lara
(20) E je ka sora lati ma yan Kainkain (sponge), Leyin ti a ba ti we Ose tan
(21) E je ka sora lati ma nu Omi ara wa, leyin ti a ba we Ose tan. Omi naa gbodo gbe mo wa lara

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

Leave a Reply

Translate »