ila kiko Nile Yoruba
Bi a ba wo oju opolopo awon omo orile-ede Naijiria, a o ri orisirisi ila loju won. Ogooro eniyan ni ko mo idi re ti a fii ko ila. Nje…
Bi a ba wo oju opolopo awon omo orile-ede Naijiria, a o ri orisirisi ila loju won. Ogooro eniyan ni ko mo idi re ti a fii ko ila. Nje…
PELE ATI ABAJA EKITI Awon wonyi yato si pele ati abaja ti a ti salaye soke nitori pe nwon gbooro pupo ju ti isaju lo.
KEKE TABI GOMBO Awon ila ti o gun ti a fa lati ori wa ti o si te woroko logangan aarin oju ati eti si isale eeke.
TURE Ila meta kekeeke looro ati meta miran ti o gun ju meta isaaju lo.
PELE Ila meta ti a fa sereke ti o duro looro. O maa nye awon ti o ba bu ila bee. A si maa npe awon eniyan bee ni “peleyeju”…
ABAJA Eyi ni awon ila meta ti a fa nibu lori ara won tabi mefa ti a to ni meta-meta nibu bakanna. ABAJA MERIN Iyato to wa laarin eleyi ati…
How powerful is Esu? ESU is very powerful such that he has a lot of task such that it is very heavy and one that make it possible for ESU…