Category: oriki

ORIKI OFFA

YORUBA – ORIKI OFFA (THE COGNOMEN OF THE OFFA PEOPLE) Short Version: Iyeru-Okin, Omo Olofa Mojo, Omo Olalomi, Omo abisu Joruko , ijakadi loro toffa toffa, Ija kan ijakan ti…

ORIKI IJEBU

YORUBA – ORIKI IJEBU (THE COGNOMEN OF THE IJEBU PEOPLE) Ijebu omo alare, omo awujale, omo arojo joye, omo alagemo ogun woyowoyo, omo aladiye ogogomoga, omo adiye balokun omilili, ara…

ORIKI AINA

ORUBA – ORIKI AINA (ENI TI AKO GBODO NA) (The panegyrics of the Yoruba female child with the umbilical cord woven around her neck at birth) Aina orosun Aina oroyinyin…

ORIKI OJO

ORIKI OJO (The panegyrics of the Yoruba male child born with the umbilical cord woven around his neck at birth) Ojo olukuloye, Ojo yeuge, Alagada ogun Ojo ja loja o…

Oríkì Onílù

Oríkì Onílù Ọmọ afi gúdúgúdú ṣ’ọlá, Ọmọ afi dùndún ṣ’ ọrọ̀, Ọmọ Àyándìran. Bí baba mi ti ńlù, Bẹ́ẹ̀ ni ṣaworo ìlù rẹ̀ ńdún, Ọmọ alùlù gbowó. Baba mi ni…

Translate »