Yàrá kótópó gba ogún ọ̀rẹ́ (learn insight from this proverb)
Yàrá kótópó gba ogún ọ̀rẹ́, bí ìfẹ́ bá wà láàárín in wọn. / A little room is good enough for 20 friends, if there is love among them.
Yàrá kótópó gba ogún ọ̀rẹ́, bí ìfẹ́ bá wà láàárín in wọn. / A little room is good enough for 20 friends, if there is love among them.
Òwe: Àgbàtán làá gb’ọ̀lẹ, bí a bá d’áșọ fún ọ̀lẹ, àá paá l’áró. Literal Translation: A lazy person must be helped completely, when we gift a lazy person clothes, we…
Rírà ni í kẹ́yìn pupa ọ̀gẹ̀dẹ̀ tí kò bá rí ẹni jẹ ẹ́. / Rottenness is what ends the life of a ripe banana, if it gets no one to…
Bí a bá fi àgbò fún eégún, à á jọ̀wọ́ okùn rẹ̀. / If we hand over a ram to the masquerade, we must release the tethering rope to the…
Ewúrẹ́ tó lè kígbe jù, kọ́ lebi ńpa jù. / The goat that bleats the loudest, is not necessarily the most famished.
,Àgbẹ̀ tó jẹun yó tó fọ́ akèrègbè ti gbàgbé pé ọjọ́ òǹgbẹ ṣì ḿbọ̀ / A farmer who ate, had his fill, and broke the water gourd forgot that days…
Ọlọ́run á mú olè, ṣùgbọ́n òtútù á pa aláṣọ. / God would eventually apprehend the thief, but the owner (whose clothes were stolen) would catch a cold.
Ìrọ̀rùn igi ni ìrọ̀rùn ẹyẹ. / The peace of the tree is the peace of the birds that perch on it.
Àgbàlagbà tí ò kẹ́hùn sọ̀rọ̀ bá ọmọ wí ní kékeré, á kẹtan sáré lórí ọmọ náà tó bá dàgbà, tí ẹnu ò káa mọ́. / An elder who won’t sharply…
A kì í fi oró yán oró; aforóyánró kì í jẹ́ k’óró ó tán; afìkàsànkà kì í jẹ́ ki ìkà ó tán bọ̀rọ̀. / Do not repay evil with evil;…