Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba.
Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii:
(1) Ohun isale
(2) Ohun aarin
(3) Ohun oke
Bi a ba n ko ede Yoruba sile, a maa n lo awon ami ohun lati ya awon ohun Yoruba wonyii soto.
Fun apeere:
Ohun isale = ami ohun
Ohun aarin = ami ohun –
Ohun oke = ami ohun /
Lopolopo igba, o maa n wulo fun akekoo lati lo awon ami ohun orin ti a ko sisale wonyii lati ranti awon ami ohun Yoruba.
Ohun isale = ami ohun = d (do)
Ohun aarin = ami ohun – = r (re)
Ohun oke. = ami ohun / = m (mi)
Ami ohun isale:
(i) konko (dododo)
(ii) asa (dodo)
(iii) ojo (dodo)
(iv) akalamagbo (dododododo)
Ami ohun aarin:
(i) aso (rere)
(ii) eran (rere)
(iii) sobolo (rerere)
Ami ohun oke:
(i) ranti (mimi)
(ii) boya (mimi)
(iii) lagbaja (mimimi)
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.