Promiscuity is an Abomination for the Wives of Priest
Ẹni ti o fini peni
Òun ni gba Obìnrin odẹ
Ènìyàn tí o fi ènìyàn pe ènìyàn
Òun ni gba Obìnrin Isegun
Ẹni tó kó ẹrù sí kòtò
Ó wá gegele wá mú osuka
Òun ní gba Obìnrin Babaláwo
Adifafun Ogirisasa Àgbẹ̀
Tí yóó gba Obìnrin Èdú
Ẹ̀rùn yi lẹ o mọ èdú ní baba.
TRANSLATION
A person who lack respect
Is the one that snatch the wife of the Hunters
A person who does not have regard for anyone
Is the one that snatch the wife of Herbalists
A person who is ready to die
Looking around for trouble
Is the one that snatch the wife of Babalawo
Casted divination for Ogirisasa Àgbẹ̀
Who would snatch the wife of Èdú (Orúnmìlà)
It is this drought season you will know Orúnmìlà as the Father.

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »