Eyan Oro Ninu Gbolohun

Eyan Oro Ninu GbolohunEYAN ORO NINU GBOLOHUN

Eyan oro ni oro ti a maa n lo lati fi yan gbolohun tabi ti a maa n lo lati fi fun gbolohun ni itumo ti o hunna ti too si yee olugbo daadaa. Lopolopo igba, a le pe eyan ni oro apejuwe.

Oro – oruko tabi aropo – oruko ti o ba n sise eyan ninu gbolohun ni a maa n pe ni eyan oro oruko.

Awon oro ti a fala si labe ni eyan ninu awon gbolohun wonyi:-

1.     Maalu Fulanisalo

2.     Ounje Adetobi

3.     Awa Okunringbon ju Obinrin lo

4.     Eyin Omodeferan ere sise

5.     Iya milowo

6.     Iwe re ti ya

7.     Ore re ni Dada

8.     Ise yin we omo mi

9.     Ile itaja yiitobi

10.            Ewu naadara pupoEYAN ORO NINU GBOLOHUN

10.            Ewu naadara pupo

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Post a Comment

Translate