Ibanisoro Lailo Oro Enu 
Ninu asa ti o se Pataki julo ni ede Yoruba ni biba ara eni soro lailo oro enu. Awon Yoruba tile ka omo ti o ba mo oju tun mo ti o gbon ti o si ni aye gidigidi. 
Yoruba le so igba oro lailo oro enu rara. Omo ti o mo oju ni omo ti a ba soro pelu oju tabi ara ti o si gbo.
Lara awon ona Pataki lati soro lailo oro enu ni:
(1) Ilu: Ni aye atijo, ilu lilu ni awon baba nla wa fi wa n ran se oju ogun. Bi ija ba si gbona awon onilu yoo ma fi ilu ki awon asaaju ogun won maa n fi ilu korin, pa owe, ko ewi.
(2) Agogo: Gbogbo ohun ti a la se pelu ilu – lilu naa ni ale se pelu agogo.
(3) Iwo fifan ati Fere Kakaki: Bi a ba n so nipa fere, eyi le je fere gbigbe, fere kakaki, fere etutu. Enikeni lo le fon fere gbigbe, aiis oba lo ni fere kakaki, awon ode lo ni fere etutu; awon tun le lo fere tiwon nigba ti won ba n sun ijala.

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »