EBA: Eba je ounje Pataki ni ile Yoruba ati kaakakiri. O je ounje ti a maa n saba je ni ile Yoruba ko si omo bibi ile Yoruba to le se lai je eba laarin ojo meji.orisirisi obe bii obe efo,gbegiri,ebolo tabi obe eeyi ti o wu yin.
*IRESI: IRESI JE OUNJE TO SE PATAKI JU NI GBOGBO AGBAYE.BI WON TII PE NI IRESI NI ILE ALAWO DUDU NAA NI AWON WON SE N JE NI ILE ALAWO FUNFUN TI WON SII N FI ENU FELEFELE PE NI RICE.BI A BA FE PA TAN KI A DIN ATA DINDIN KI AWA FI IGBIN EJA GBIGBE FOO LORI.HNMMM…….OUNJE TII SOOO
*LAFUN: LAFUN JE OUNJE TO WOPO JU LAARIN AWON ARA EGBA .ONJE OKELE NI LAFUN JE AROMORA SII NI PELU.A LE FI ORISIRISI OBE JE SUGBON OBE TI O TAYO JULO PELU RE NI OBE GBURE OLOBORO ATI ERAN TABI EJA A SI LE FII GBONMO GBE SOFUN.
*IYAN: awon Yoruba a maa so wipe iyan to wewu egusi,to de fila isapa hnnmmm…….I-Y-A-N. a baa lowo awon baba nla wa o si je ounje to gbayi julo nile Yoruba.isu lama gun felefele ninu odo titi yo fi di iyan a le fi isapa je tabi obe egusi sugbon obe to tayo julo ni obe efo elegusi tabi riro ki a wa fi eran igbe de lade.a le fi emu ogidi sin losale.
*SAPALA: Hnmm….sapala elepo…odun yenyen.sapala je okan lara ounje Yoruba ,o jo moin-moin pupo sugbon agbado pelu ata ati epo pupa ni a fii ma n se sapala.awon elomiran a maa je lasan awon miiran a si ma mu gaari olomi tutu peli re.
*IKOKORE: Ikokore je ounje to gbajumo laarin awon ara ijebu.isu ewura ,ata,epo ati awon eronja bii ede,eja la ma fin n se ikokore yii a si le je pelu eba tabi okele tomba wun nii.
*EBIRIPO: Ebiripo je onje to se koko fun awon ara ijebu.isu koko ni a ma fi n se ebiripo a sii pon sinu ewe sori ina bii eni pon moin-moin.obe eyikeyi to ba wuni nii na fi n tii sonafun.
*ASARO: Asaro elepo je ounje to gbayii laarin gbogbo omo ile kaaro-o-jiire.Ako isu pelu epo pupa ati ata,eja ni a maa fi n se Asaro .aropo sii lama fii se ni ori ina.a le fi omi tutu tabi oti olomi osan tee lo si ona ofun.
*EGBO: Egbo je okan lara ounje ile Yoruba.Agbado funfunni a o se lasero petepete.a le je pelu ata dindin tabi ki a fi ororo yii pelu ewa aganyin.
*OFADA: Ofada je iresi ile Yoruba ti o sii maa n muni datami.ile Yoruba nii a ti n gbin a sii ma se bii eni se iresi gangan.Ata dindin to ta lenu sue-sue pelu awon eronja bii igbin,eja gbigbe pelu eran tabi ponmo dee lade.
*EWA AGANYIN:Ewa aganyin naa wa lara ounje to se koko ni ile Yoruba.a o se ewa naa lasero ti yo fo petepete.a o wa din ata re ni adin dudu. O dara pelu boogan tabi isu bibo tabi dindin.
*MOIN-MOIN: Moyin-moyin….ounje to wuyi ni ile Yoruba.ewa lilo ni a fi n se moin-moin bi a ba fe wa pa kuu, ki awa lo run ede ati eja osan sinu re ki a si wa fi ewe pon sori ina.haaa….ounje deee.a le fi buredi, ogi,eko tii sofun.
*PUPURU(FUFU): pupuru dabi fufu,ile ondo ni a maa ti n saba jee. Iyato to wa laarin oun ati fufu ni wipe a maa n yan pupuru lori ina nii.a sii le je pelu obe ila alasepo
*AKARA ELEPO: Akara elepo wa lara ounje to fajumora ni ile Yoruba.Ewa, ata, ni a o loo pelu alubosa lati fii mu adun re po yoyo, a o wa din lori ina pelu epo pupa. A le je pelu eko,boogan tabi ki a mu pelu gaari olomi tutu.
*EWA ADARU: Ewa adaru naa je okan lara ounje ile Yoruba ti o dun ti o si fajumora.Ewa ati agbado ni a maa n se papo lori ina ti a si ma n fi epo pupa dabira sii loju.gaari lebu lo fakoyo pelu ree .
*OFULOJU:Ofuloju je okan lra ounje Yoruba to gbamuse.ewa funfun pelu alubossa nikan la o lo ti a o sip on sinu ewe lori ina.a o wa fi ata dindin ti a ti fi orisirisi eronja ge fila le lori
*EMOOYO: Emooyo je obe fun awon ara eko.eja tutu ni a ma fi n se obey ii a si le fi je okele eyikeyi ti o ba wun nii.
*EWA ATI DODO:Ewa ati dodo je ounje Yoruba ti o fojumora pupo.a o se ewa,a o wa da dodo dindin tabi bibo lee.a le je lasan a si le je pelu boogan.
*ISU SISUN ATI EPO:A ba ninu itan mo aroba wipe awon agbe ni won koko bere sini je iru ounje yii nigba tie bi ba n pa won loko,won a ya mu isu sun won a si gba epo pupa tabi ki won je pelu epo bee.nisinyi o ti di okan lara ounje Yoruba to gbajumo.
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Related Post
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.