Tuesday, December 12, 2023

Spiritual work using cat eye - Oju olongbo

SHARE
Iba agba o



Uses of Oju olongbo (cat eyes) 

Die Lara iwulo ESO oju olongbo,



1: Ifunra (body__Teller)
Ao mun ESO oju olongbo kan, ESO olonsepetu kan na, (opa_esu), omo Atare kan, Ao lo papo Ao fi singbere kan soso sii Aya.... 

2.. Eyonu {Favor}
ESO oju olongbo mesan 9
Omo Atare mesan 9, Ao lo papo Ao fii singbere EJIOGBE SII APA OSI NIKAN,  ODAJU

3, Afoibon (to break gun)
ESO oju olongbo 16, 
Omo Atare 16, Ao lo papo, Ao fi singbere yipo APA mejeji ,, ODAJU PA

4, Ayeta ibon TODAJU
ESO oju olongbo mesan 
ESO omo irula mesan
Oju eyele mejeji, 
Karahun igbin die, Ao lo papo Mon Ara won,, 
Ao fii singbere Ejiogbe Mesan sii Aya ati Eyin wa ..

5, OGUN IBON AGBEKORUN
ESO oju olongbo mesan
Omo Atare mesan
Arigisegi to wa ninu ile, 
Ao ko awon ESO yi sinu Iwo arigisegi na, Ao di ni ikobere ... 
Ao GBE korun, 

Ao ma WO singlet tele aso wa, ao sese wa GBE korun, 

6, gbere ajeegun omo yahoo, 

Ao bo eepo inu ESO oju olongbo meta kuro ao wa lo yellow inu re Mon omo Atare meta, pelu eepo obo die, ao.lo kuna 
Ao fi singbere sii orikerike ara ...  ATUDE NII..


This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: