Oyeku meji
Speaks against polygamy
If you are born under this odu, you must never marry more than one wife or engage with more than one lady . Also you must only be with black or dark skin lady .
Ọ̀kan ṣoṣo póró lobìnrin dùn mọ lọ́wọ́ ọkọ
Bí wọ́n bá di méjì
Nwọn a dòjòwú
Bí n wọ́n bá di mẹ́ta
Nwọn a dẹ̀ta ǹtúlé
Bí n wọ́n bá di mẹ́rin
Nwọn a di ìwọ lo rín mi ni mo rín ọ
Bí n wọ́n bá di márùn-ún
Nwọn a di lágbájá ní ó run ọkọ wa tán lóhun susuusu
Bí n wọ́n bá di mẹ́fà
Nwọn a dìkà
Bí n wọ́n bá di méje
Nwọn a dàjẹ́
Bí n wọ́n bá di mẹ́jọ
Nwọn a di ìyá alátàrí bàm̀bà
Ló ti kó irú èyí ṣẹ ọkọ wa lọ́wọ́
Bí n wọ́n bá di mẹ́sàán
Nwọn a di ìyáálé wa ò níṣẹ́ kan
Kò lábọ̀ kan
Bó bá ti jí
Aṣọ ọkọ wa níí máa san kiri
Bí n wọ́n bá di mẹ́wàá
Nwọn a di ilé ni ọkọọ wá jókòó
Ni nwọ́n ń wá ọkọọ waá wà
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment