1. Ó ní kì n jade síta, can you imagine? (instead of: Ó ní kì n jáde síta, ṣé o lè gbàgbọ́?)
He/she said I should get out, can you imagine?
2. Ó gbá etí mi, what an insult? (instead of: Ó gbá etí mi, irú àrífín wo nìyẹn?)
He/she slapped my face, what an insult?
3
. Mo ti ba yin pick call yín (instead of: mo ti bá yín dáhùn èrọ ìbánisọ̀rọ̀ yín)
I have picked/answered your call for you.
4. Mo máa attend meeting yẹn (instead of: mo máa lọ sí ìpàdé yẹn)
I will attend the meeting.
5. Situation wọn máa to improve (instead of: Ayípadà máa tó dé bá wọn)
Their situation will soon improve.
Reference:
Ọ̀párìndé K.M, Language Endangerment: The English Language Creating a Concern for the Possible Extinction of Yorùbá Language,
Journal of Communication (July 2017)
Post a Comment