ORIN ÒSUN
Mo b'ọ́sun lódò tí ń wẹmọ
Ó kúkú dàbí n gbé kan Òtòròmẹ̀fọ̀n
Ìyá yèyé o
A fi idẹ rẹmọ
Ore yèyé o
A fi idẹ rẹmọ.
TRANSLATION
I met Òsun in the river bathing her babies
I felt like carry one of her babies ( Otoromefon)
The Queen mother
Who uses brasses to comfort her babies
Ore yèyé o
The one that uses brasses to comfort her babies.
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment