Showing posts with label proverb. Show all posts
Showing posts with label proverb. Show all posts

Friday, June 30, 2023

Tí ẹṣin bá dá'ni

Tí ẹṣin bá dá'ni

Tí ẹṣin bá dá'ni, a máa ńtun ùn gùn ni. /


If one is thrown by a horse, one ought to remount it again.



[If you try and fail, try again: if you don't try and keep trying, you can't win; it's not how many times you fall that counts, but how many times you get up.]
Àjùmọ̀bí ò kan t'àánú

Àjùmọ̀bí ò kan t'àánú

Àjùmọ̀bí ò kan t'àánú; ẹni orí rán sí'ni ló ńṣe'ni lóore /



To be related to someone by blood does not guarantee receiving his or her support; help comes only from those divinely sent to one.


[Help, when it comes, may not necessarily be from expected sources; keep an open mind]
Bí kùkùté ṣé kéré tó

Bí kùkùté ṣé kéré tó

Bí kùkùté ṣé kéré tó, kò sí ẹni tó lè fi ẹsẹ̀ fà á tu. /


As small as the tree stump is, no one can uproot it with the foot.



[Judge nothing by its appearance; underestimate nothing; what we deem inconsequential may well pack a hefty punch.]
Bí imú asín bá gùn

Bí imú asín bá gùn

Bí imú asín bá gùn, ẹnu ẹlẹ́dẹ̀ kọ́ ló yẹ ká ti gbọ́. /


Even if the moonrat has a long nose, it is not the place of the pig to point it out.



[Don't meddle: mind your own business; don't criticise others with far less issues than you are grappling with.]
Ìbàjẹ́ ènìyàn

Ìbàjẹ́ ènìyàn

Ìbàjẹ́ ènìyàn, kò lè dá iṣẹ́ Olúwa dúró. / 


The nefarious acts of man cannot scuttle the plan and purpose of God. 




[Keep hope alive; man cannot be more than man, yet God remains God; keep moving forward, undeterred.] #
Tí a bá ní ká tì í kó dúró

Tí a bá ní ká tì í kó dúró

Tí a bá ní ká tì í kó dúró; tí a bá tì í tó bá ṣubú, ńkọ́? /


If we intend to push it to stand; what if we push it and it falls?



[Think well before you act; don't be presumptuous; things often have the propensity not to go as planned: why moderation is crucial in everything.]
Nítorí ogun àtẹ̀yìnjà

Nítorí ogun àtẹ̀yìnjà

Nítorí ogun àtẹ̀yìnjà, ni pẹ́pẹ́yẹ ṣe ńkó  ọmọ rẹ̀ sí iwájú. /


Because of wars (or mishaps) which may proceed from the back is why the duck keeps her ducklings ahead of her. 




[Be strategic: anticipate the future and plan ahead,]