Friday, June 23, 2023

AKIRIBITI ẸBỌ / BIG OFFERINGS (ÒKÀNRÀN ÒFÚN)

SHARE
AKIRIBITI ẸBỌ/ BIG OFFERINGS


May Irúnmolè accept our today's offerings.

Ifá ní:

Ọ̀sẹ́ pàá bí ọkọ́
Iwori jọ̀wọ̀lọ̀ bíi rádò
Adifafun Ọrunmila yóó rán akiribiti ẹbọ lọ sí alade òrun nitori ọmọ rẹ
Ẹbọ ni awo pe ki o ṣe
Ó sì gbẹbọ lọpọlọpọ o rúbọ

Ẹbọ, mọ gbàgbé o jiyin
Akiribiti o, mo gbàgbé o jiyin
Akiribiti
Bi o bá d'ọrun ti o bá jiyin ajé 
Ki a rájé rere ní
Akiribiti, mọ gbàgbé o jiyin
Akiribiti
Bí o bá d'ọrun ti o bá jiyin aya
Ki a rí aya rere ní
Akiribiti, mọ gbàgbé o jiyin
Akiribiti

Bí o bá d'ọrun ti o bá jiyin ọmọ
Ki a rí ọmọ rere bí
Akiribiti, mọ gbàgbé o jiyin
Akiribiti
Bi o bá jiyin ilé
Ki a rile rere kọ
Akiribiti, mọ gbàgbé o jiyin
Akiribiti
Bí o bá d'ọrun ti o bá jiyin
Ki a rí ire gbogbo ni
Akiribiti, mọ gbàgbé o jiyin
Akiribiti.

TRANSLATION

Ọsẹ pàá bí ọkọ́ (Ọsẹ break like hoes)
Iwori jọ̀wọ̀lọ̀ bíi rádùn (ìwòrì look like thunder stone)
Casted Ifá divination for Orúnmìlà who would send akiribiti ẹbọ (big offerings) to the Heaven because of his devotees
The Ifá Priests advised him to perform sacrifices

He performed the sacrifices
Ẹbọ, don't forget to deliver messages
Akiribiti o, don't forget to deliver our messages
Akiribiti.
When you reach Heaven and deliver message of Ajé
We shall have good wealth
Akiribiti, don't forget to deliver our messages
Akiribiti

When you reach Heaven and deliver message of wife/husband
We shall have good wife/husband
Akiribiti, don't forget to deliver our messages
Akiribiti.
When you reach Heaven and deliver message of babies
We shall have good babies
Akiribiti, don't forget to deliver our messages

Akiribiti
When you reach Heaven and deliver message of house
We shall build good house
Akiribiti, don't forget to deliver our messages
Akiribiti
When you reach Heaven and deliver message of all blessing
We shall have all blessing


Akiribiti, don't forget to deliver our message
Akiribiti.
 
THE STORY

Orúnmìlà went to consult Ifá because of his children and devotees. His children could live long in good health and wellness, they could have money, wives, babies, build houses,

buy horses and live comfortable on Earth was why Orunmila consulted Ifa. 

The Ifá Priests advised Orúnmìlà to perform Akiribiti Ẹbọ, BIG SACRIFICE for his children and devotees for them to be well equipped for their needs on EarthThey told him to send this sacrifices to the Heaven.

Orunmila performed all the sacrifices recommended for him. The big offerings of Orunmila landed in the Heaven. The Alásùàdà in the heaven checked the Ẹbọ that Orunmila performed for his children.


They said that Orunmila wanted his children and devotees to have Ajé, Aya/Ọkọ, Ọmọ, Ilé and all kind of blessing. 

The Alásùàdà in the Heaven accepted the sacrifices of Orunmila. The children and devotees of Orunmila started getting their needs

They are having money, wives, babies, houses and enjoy all blessing in the Universe.

Abọru abọye o
Ẹbọ yóó máa fin o
Ètùtù yóò sì máa gbà.

@ ÒKÀNRÀN ÒFÚN 2023
AWOLADE IFÁTAYO A.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: