Ewé Ifá
Ewé Ọdundun
Ibi tutu laba Ọdundun
bi odun baa ti dun ni Ọdundun dun
Ọdundun mi waa de o
a so ode dero
ti oba le fun gbogbo ewe ko
ọdọ́ ọdun ni won pa oruko da
odundun ni ki pa oruko ti e da
Odundun a so ode dero
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment