Gígún ni à ń gúnyán ní ilẹ̀ Yorùbá. Oríṣiríṣi ọbẹ̀ bíi ẹ̀gúsí, ẹ̀fọ́ rírò, ilá, ààpòn abbl. ni a fi ń jẹ Iyán.
Oríkì Iyán
Iyán funfun lẹ́lẹ́,
Ọba nínú oúnjẹ,
Ìjòyè àtàtà láwùjọ òkèlè,
Iyán tó wẹ̀wù òsíkí,
Tó dé fìlà ìṣápá,
Aràn má délé ọ̀lẹ,
Àjẹ pọ́nnulá,
Àjẹ b'ọ́kọ dọ́rọ́ ẹ̀rín,
Iyán loúnjẹ, ọkà loògùn
Ọ̀rẹ́ ẹ̀gúsí, alábàárìn ẹ̀fọ́
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment