OJÚLARÍ
Ojú ò ṣe fi mọ̀ ìwà ẹ̀dá,
Inú ẹ̀dá ò dàbí òde,
Bí ẹ bá rí ènìyàn,  ẹ sọ́ra fún wọn
Ẹni a ba ñ bárìn ká fura si,
Ẹni a bá fura sí ka yẹra fún wọn
Torí Ojú wa ko Ojú, ẹsẹ̀ wa ko ẹsẹ̀, 
Ọwọ́ wa bọwọ́
Ṣùgbọ̀n Inú wa o konú, 
Oníkùn ló mọ ìkà.

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »