A ma n ki oba pe:
Kabiyesi, alase ekeji orisa.
Kia de pe lori.
Ki bat ape lese.
E o je ju ara iwaju o.
Awon Oloye la nki pe:
Ebo a fin o
Eru a da
Baba re a gbe e o.
E ku eto ilu.
Ori awon oba ati oloye ma n ya bi a ba nki won bayi, nitoripe a fi han pe a mo riri ipo won.
Bi a ba farabale wo daadaa, a o ri wipe kikini lede Yoruba ko lopin be si ni idahun wok o si lonka.
Asa yi ti wa di ajebi, ko si ohun ti o le gba a sonu lowo wa, bi o tile je wipe opo omo bibi ile Yoruba lo ti n te asa na mere sugbon “igbo kii di ka a ma mo Iroko, oja kii di ka a ma mo afin.”
Bi o ti wu ki oju la to, a ko ni saimo omo Yoruba tooto lawujo nibi won gbe nki ni.
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::
IFA consultation and Divination
Egbe Orun initiation
Appeasement of Egbe Orun
Yes and No questions
Feeding of Ori (inner head)
Feeding of ORISA
IFA INITIATION
Solutions to Problems
Source: https://www.orisa.com.ng
0 $type={blogger}: