Spiritual Usage of alligator pepper
Such person should eat atare (alligator pepper) before he recite it.
The prayer goes thus.
A mon Ana
A mon oni
A o mon Ola
Botunla omo iya re
Bi o suhan bi ko suhan
A ko mon
A difa fun Orunmila
Ifa yi o raga bo omo re bi igun Igemon
Ifa raga bo mi
Ewe oori ni raga boori
Ifa raga bo mi
Ewe etipa elila ni raga bo Ile
Ifa raga bo mi
Nitori bi adiye ba pa omo tire
A raga bo o
Ifa raga bo mi
Bi omi nla se raga bo yanrin lodo
Orunmila raga bo mi
Bi ikan se n raga bo olu ogan
Raga bomi lowo riri ati airi.
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.