Tuesday, April 2, 2024

OBA ELEYE

SHARE
Oba ELEYEIpo oba ELEYE wa fun eyan to ti rin aye ja.
Won kii Dede Fi enikeni si ipo Yi nitori agbara to wa ni di e.

Ipo agbara Yi ma n sofo lopo lopo igba, ko da ole sofo fun egberun odun TABI Jube lo ti ti ti won a Fi ri Eni ti o Leto si ipo Yi .
Eni ba je oba ELEYE ma ni Fe awon IYAAMI ELEYE ATI IYAMOPO bi isan orun.


Ko da , yio je akin kanju eniyan to feran lati ma se eto re fun awon IYAAMI ELEYE ati IYAMOPO ATI fun gbogbo awon ÒRÌSÀ.


Ohun to je iyalenu julo ni wipe, OBATALA ni alase to ma n Yan oba ELEYE ni igba ki gba ti ipo Yi bati sofo.

OBATALA nikan lo lase ATI fa eyan sile.Leyin ti OBATALA ba ti fa eyan sile, awon ÒRÌSÀ toku aba bere sini Dan onitoun wo.

To ba yege lowo idanwo awon oosa. Won ma gba wole lati di oba ELEYE.


Ti koba yege ajepe OBATALA atu Fi suru wa elomi


Akiyesi Pataki nipe awon ÒRÌSÀ Yi ko ba irawon ja ija kankan . Gbogbo won wa ninu irepo ATI ife.


Koda won n jeun ninu awo kaan-an-na.


Eni ba je oba ELEYE gbodo mo ofin gbogbo aye PATA PATA nitori pe olofin ni awon IYAAMI ELEYE ati IYAMOPO.


Ipo agbara to ju agbara lo ni oba ELEYE to fi je pe ekan ninu odun egberun Lona egberun ni won ma n Je.


Okunrin lo ma n Je oba ELEYE. Ipo Yi kii se ipo obirin.


Eni ba je oba ELEYE, Onitoun ti Fe gbogbo eye PATA PATA.


Eje ki n Danu duro bayi....Oruko mi ni AJE NLA
Omo OBATALA.
www.orisa.com.ng

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: