II II
I II
II I
II I
Okara okoro, omi inu igbin o gbę;
Lo difa fun olooto Omi Ayé;
Okara okoro, omi inu igbin o gbę;
Lo difa fun şikaşika Omi Ode Orun;
Otito bale o di omi;
Ika bale o di yangi.
Otito Olufę lo to ki a maa şe.
Olotito a ba otito rin;
Şikaşika a si ba ika wolę.
Otito gbe ni, o gbe ni ju ika lo.
Nitori, otito lo gbe Molę de 'Fę.
Ęlaboru, Ęlaboye, Ęlaboşişè!
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment