ÁJE OLOKUN ASỌ AGBA DÉWE
AJE OLOKUN ASỌ EWÉ DAGBA
OGUGU LÚSỌ
TI TẸRU TỌMỌ NFOJO JUMỌ WÁ KÍRÍ
AJÉ OLOKUN ASỌRỌ DÁYỌ
AJÉ ÍWỌ LÁ NJÍ KÍ, IWỌ LA NJI RÍ,
ÍWỌ LÁ NJÍ KẸ́, IWỌ LÁÁ NJÍ PÉ
IWỌ LÁBỌMỌ TÍ NBORI AYÉ
IWỌ LÁ NMÚ SOKÚN, IWỌ LÁ NMÚ SEKÉ
IWỌ NI ANÍRỌPO , Ọ́BÁ TÍ NKO NA
YANRÀN YANRÀN, YANRÀN
ÁJÉ O, AGBA ORISA JẸ KÍN NI LỌWỌ
MÁ JẸ KI N NI Ẹ LỌRUN
AJE WA FILE MI SE IBU GBÉ OOOO (ÁMÌN)
Post a Comment