Oriki Eko, Oriki Ilu Eko
Eko Akete Ile Ogbon
Eko Aromi sa legbe legbe
Eko aro sese maja
Eko akete ilu okun alagbalugbu omi,
Ta lo ni elomi l'eko? ebiwon pe talo ni
abatabutu baba omikomi, talo laabata
buutu baba odo kodo
Eko adele ti angere nsare ju eniyan elese meji lo
Eni to o ba lo si ilu eko tiko ba gbon, Koda,
bo lo si ilu oyinbo ko legbon mo
Afefe toni pon wa ni bebe okun ti yin,
faaji to ni pan wa ni bebe osa
Eko omo osha nio ose, mase kutere,
osha n gbobi, kutere n gbori
Eyin lomo afinju woja marin gbendeke,
obun woja n wapa sio sio
Eyo o Aye'le Eyo o,
Eyo baba n teyin to n fi golu n sere, eyin oni sanwo onibode,
odilee
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment