ORIKI OBATALA (ORISA NLA)
Baala o
Oro oo r’ Elu
Igbin gbomo la
Igbin omo akoro
Otu koko Ala f‘ omo tore
Osun sile f’oje tikun
Onile ji, Oje o ji
Ogbagba ti f’ owo ala gbale
Irin kobokobo a fi n bowu
O gbaa giri danu lowo osika
O fo osika loju afota
O le odale kanu owu bara bara
Awoni pepe bi enirini
Alapata okunrin asa eran mo egun
A je eku bi onirin
O je eja bi igere
Akorin mu otin
Ayena j’ obi
Afun ni mo towo eni
O fun nini, gba fun aini
O so enikan di igba eni
Alase Oba afase soro
Ibante funfun
Sokoto funfun
O l’ epo nile je ila funfun
Onile oju opo
Eleta iranje
Alade sese efun
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment