ISE ILU LILU
Ise abinibi ni ise ilu lilu je fun awon iran ayan.kaakiri ile Yoruba ni ise yii gbajumo.Ibi ti won ti n se nnkan eye,odun ibile,ni won ti n lulu.Amuludun ni awon onilu je.Ibi ti won ba ti n lu ilu,orin ati ijo kii gbeyin nibe.Ise idile ni ise ayan je sugbon won tun maa koi se ilu naa.
A le pin ilu si meji gege bi lilo won.Awon ni :
1) Ilu fun Odun Ibile
2) Ilu fun Ayeye
ILU FUN ODUN IBILE :
ILU |
ORISA TO NI |
Bata |
Sango, Egungun |
Ipese/ipesi |
Ifa |
Agere |
Ogun |
Igbin |
Obatala |
ILU FUN AYEYE :
Dundun |
(neta ni won) Awon ni iya ilu,kerikeri,Gangan,Omele,Kannango,Gudugudu |
Awon miiran |
Ibenbe,Kiriboto,Gbedu,Koso,Apini (meta ni ) Iya-ilu Omele ati Agogo, Sakara,Sanba,Apepe,Agogo,Agidigbo,Sekere |
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.