ISE AGBE
Ise agbe je ise ti o gbajumo ju lo ni ile Yoruba.Ise agbe se Pataki nitori awon ni won n pese ounje fun ara ilu.
Awon agbe ni won n gbin ere oko bii paki, ere/ewa, isu,agbado,ata, efo ewedu,epa ati bee bee lo.A le pin agbe si orisi meji .
(i) Agbe Alaroje (small scale faming) :Agbe alaroje ni awon agbe kekeke ti won n da oko etile fun jije ara won.
(ii) Agbe Aldaa-nla (large scale farming) :Agbe Alada-nla ni awon ti won n dako egan,ti won n fi ise agbe sise se.
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.