ORO AYALO NINU EDE YORUBA
Oro ayalo (oro- ti- a- ya lo) ni oro ti a ya lati inu ede kan wo inu ede miiran ni ona ti pipe ati kiko re yoo fi wa ni lbanu pelu batani iro ede ti a ya a wo.
A n ya oro lati sapejuwe asa tuntun ti a n ba pade ni pase owo, iselu, imo ero, imo sayensi, esin, eti amuluudun laarin awon ti n so ede kana ti elede miiran. Ni Pataki oro ayalo maa n je ki ede kun si.
inu awon ede ti yoruba ti ya ede lo ni :
EDE |
APEERE ORO TI A YA WO EDE YORUBA |
Geesi |
Buredi, Fulawa, sikeeti, sitoofu abbl |
HAUSA |
Wahala, alafia, mogaji, labara, ankali, abbl |
Faranse |
Sinmi, taba, abbl |
Larubawa |
Alubarika, Alubosa mogarubi, anjonu, mojesi, mekunu |
Inu edeGeesi ni Yoruba lati ya oro julo, idi abojo ni wi pe.
(i) ajosepo ojo pipe ti wa laarin ijoba Geesi ati ile naijiria
(ii) ati pe ede Geesi lo tun je ede ijoba orile- ede Naijiria tan ihun ede Yoruba ati oro ayalo
Awon oro ti a ya wo inu ede Yoruba gbodo wa ni ibamu pelu batani bi a ti se n ko awon ina ede Yoruba sile
Bi apeere:
i) Konsonanti ki pari silebu tabi oro Yoruba
ii) Isopo konsonanti ko gbodo waye ninu silebu ede Yoruba
iii) Gbogbo oro ayalo ni a gbodo lo ami ohun si ni ori
iv) Inu oro ayalo gbodo tele ilana apele koofo: Kf tabi FKF
v) Ohun oke ko le bere oro yoruba onibatani F1 – KF2 ati pe
vi) Faweli aranmupe ko le je F1 ninu oro onibatani F1 – KF2
EDA ORO AYALO
Orisii ona ti a le gba ya oro lati inu ede Geesi we inu ede yoruba ni yala nipa ilana afetiya ati afojuya.
1. ILANA AFETIYA : – Eyi ni ki a tele ilana bi ase fie ti gbe bi oro ti dun tabi bi awon elede se pee
Bi apeere :
Tailor – Telo
Bible – baibu
peter – pita
2. ILANA AFOJUYA: – Oro ayalo afojuya ni awon oro ti a ya nipa ti tele ilana bi awon elede ti a ti y a won se n ko awon oro bee sile.
Bi apeere: –
Table – Tabili
Milk – miliki
Bible – Bibeli
Awon oro Ayalo Kanwa ti won ni eda afeti ati afojuya
Bi apeere: –
ORO GEESI |
AFETIYA |
AFOJUYA |
Peter |
pita |
Peteru |
Contractor |
kongitato |
Kontiracto |
inspector |
Ripeto |
Ihinsipekito |
Esther |
Esita |
Esiteri |
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.