ila eke tan pe ni Abaja

ABAJAEyi ni awon ila meta ti a fa nibu lori ara won tabi mefa ti a to ni meta-meta nibu bakanna.

ABAJA MERIN


Iyato to wa laarin eleyi ati eyi to ea loke yi ni pe. A bu ila toke ni meta-meta, sugbon a bu eleyi ni merin-merin.
ABAJA ALAGBELEIru abaja eleyi ni a ma n bu si oju eniyan ti a si tun gbe meta oro miran le lori

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Post a Comment

Translate