Saturday, January 27, 2024

Ọ̀wọ́nrínṣogbè

SHARE
Ọ̀wọ́nrínṣogbè ní kí a fi oun Èṣù fún Èṣù… Gbọn-gbọn-gbọn ni wọ́n rọ’kọ́
Gbọ̀n-gbọ̀n-gbọ̀n ni a rọ àdá
Léjìdà-léjìdà ni wọ́n rọ agogo idẹ
A d’ifá fún Alárè Ohùn Tótó


Alárè Ohùn Tótó
Ọmọ a bu erin bí ẹni tí ńbu’ṣu

Ọmọ a bù kan gẹ̀dẹ̀gbẹ̀ tẹ́lẹ̀ kòkò
Bí wọ́n ti ńjẹ Alárè wọn ò tọ́jọ́
Wọ́n ní kí wọ́n dúró ní ‘dúró, kí wọn ó bọ odó
Wọ́n ní kí wọ́n bẹ̀rẹ̀ ní ‘bẹ̀rẹ̀, kí wọn ó bọ ọlọ
Kí wọ́n dúró lóòró gangan, kí wọn fi oun Èṣù f’Èṣù


Èṣù Olugbe, Awo Láàmúlé

A d’ifá fún Láàmúlé, 
Orí ò rẹ’rù, orí d’orí ate
Èṣù gba tì ẹ, Ẹ̀gbà gba tì ẹ
Oun ẹ rí, ẹ f’Èṣù 
Èṣù gba ọlọ o
Ọ̀wọ́nrínṣogbè, k’Èṣù gba
K’ẹbọ dà f’ẹlẹ́bọ

Èṣù gbá ọlọ ẹ, gbà-gbá ọlọ o
Oun ẹ rí, ẹ f’Èṣù o
Èṣù gbá ọlọ ẹ, gbà-gbá ọlọ o

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: